Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà Republic of Angola República de Angola (Portuguese) Repubilika ya Ngola (Kikongo, Kimbundu, Umbundu) | |
---|---|
Olùìlú | Luanda |
Ìlú tótóbijùlọ | olúìlú |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Potogí |
Lílò national languages | Kikongo, Chokwe, Umbundu, Kimbundu, Ganguela, Kwanyama |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2000) | 37% Ovimbundu 25% Ambundu 13% Bakongo 22% ará Áfríkà míràn 2% Mestiço 1% ará Europe |
Orúkọ aráàlú | ará Àngólà |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira ìṣọ̀kan oníàrẹ |
• Ààrẹ | João Lourenço |
Bernito de Sousa | |
Aṣòfin | Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Ìlómìnira | |
• látọwọ́ Pọ́rtúgàl | 11 November 1975 |
Ìtóbi | |
• Total | 1,246,700 km2 (481,400 sq mi) (23k) |
• Omi (%) | negligible |
Alábùgbé | |
• 2014 census | 25,789,024[1] |
• Ìdìmọ́ra | 20.69/km2 (53.6/sq mi) (199th) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $115.679 billion[2] (64k) |
• Per capita | $5,894[2] (107k) |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $100.948 billion[2] (61st) |
• Per capita | $5,144[2] (91k) |
Gini (2000) | 59[3] Error: Invalid Gini value |
HDI (2011) | ▲0.486 Error: Invalid HDI value · 148k |
Owóníná | Kwanza (AOA) |
Ibi àkókò | UTC+1 (WAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (kòsí) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
Àmì tẹlifóònù | +244 |
ISO 3166 code | AO |
Internet TLD | .ao |
Àngólà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àngólà (Pọrtugí: República de Angola, pípè [ʁɨˈpublikɐ dɨ ɐ̃ˈɡɔla];[4] Kikongo, Kimbundu, Umbundu: Repubilika ya Ngola), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní apágúsù Áfríkà tó ní bodè mọ́ Namibia ní gúsù, Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò ní àríwá, àti Zambia ní ilàòrùn; ìwọ̀òrùn rẹ̀ bọ́ sí etí Òkun Atlántíkì. Luanda ni olúìlú rẹ̀. Ìgbèríko òde Kàbíndà ní bodè mọ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kóngò àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú ilẹ̀ Kóngò.